Skip to content

Kika Iwe Apileko Oloro Geere Ti Ijoba Yan

Igbelewon :

 • Kin ni gbolohun onibo?
 • Ko isori gbolohun onibo
 • Salaye asa igbeyawo ode-oni lekun-un-rere

Ise asetilewa: Gege bi esin re, salaye ilana igbeyawo ode-oni

 

OSE KERIN

EKA ISE:                EDE

AKOLE ISE:          Gbolohun Ede Yoruba nipa fifi oju ihun wo o.

Gbolohun je akojopo oro ti o ni oro ise ati ise ti o n je nibikibi ti o ba ti jeyo.

Gbolohun Abode/Eleyo oro-ise

Eyi ni gbolohun ti ko ni ju oro-ise kan lo.

 

Gbolohun Abode kii gun, gbolohun inu re si gbode, je oro ise kikun.

Apeere;

 1. Dosunmu mu gaari
 2. Aduke sun
 • Olu ra iwe

 

Ihun gbolohun Abode/Eleyo Oro –Ise

 1. O le je oro-ise kan Apeere; lo, sun, joko, dide, jade, wole

 

 1. Oro ise kan ati oro apola Apeere;
 2. Aniike sun fonfon
 3. Alufaa ke tantan
 • Ile ga gogoro
See also  AKOLE ISE EYA GBOLOHUN NIPA ISE WON

 

 1. d) Oluwa, oro ise ati abo Apeere
 2. Ige je ebe
 3. Ibikunle pon omi
 • Oluko ra oko

 

 1. e) O le je oluwa, oro ise kan, abo ati apola atokun. Apeere.
 2. Aina ru igi ni ona
 3. Ojo da ile si odo

 

 1. e) O le je oluwa oro ise kan ati oro atokun. Apeere;
 2. Mo lo si oko
 3. Baba wa si ibe

 

Gbolohun Alakanpo.

Eyi ni gbolohun ti a fi oro asopo kanpo mora won.

Akanpo gbolohun eleyo oro-ise meji nipa lilo oro asopo ni gbolohun alakanpo.

Awon oro asopo ti a le fi so gbolohun eleyo oro-ise meji po ni wonyi, Ayafi, sugbon, oun, ati, anbosi, amo, nitori, pelu, tabi, koda, boya, yala abbl. Apeere;

 1. Olu ke sugbon n ko gbo.
 2. Atanda je isu amo ko yo
 • Tunde yoo ra aso tabi ki o ra iwe
 1. Mo san owo nitori mo fe ka we abbl.
See also  AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE

 

See also

EYA GBOLOHUN

AKOLE ISE

AKOLE ISE EYA GBOLOHUN NIPA ISE WON

ATUNYEWO AMI OHUN ATI SILEBU EDE YORUBA

AKORI EKO: ERE IDARAYA

SUBSCRIBE BELOW FOR A GIVEAWAY

Building & maintaining an elearning portal is very expensive, that is why you see other elearning websites charge fees. Help to keep this learning portal free by telling mum or dad to donate or support us. We accept grants, sponsorships & support to help take this to the next big level and reach out to more people. Thank you so much. Click here to donate

Leave a Reply

Your email address will not be published.

School Portal NG
error: Content is protected !!