Skip to content

Yoruba

Yoruba

OSE KERIN-IN

AKORI EKO: ATUNYEWO IHUN ORO Iro konsonanti ati iro faweli pelu ami ohun ni a n hun po di oro. Orisi oro meji ni o wa ninu ede Yoruba. Awon ni: Oro ipinle; ati Oro ti a seda ORO IPINLE: Oro ipinle ni awon oro ti a ko le seda won. Apeere: Adie, eedu, omi, ori, oju, imu, eti, apa, ese, owo, ile, oba, odo, ojo, agbara, omo, iya ati bee bee lo. Abuda Oro Ipinle Oro-ipinle maa n ni itumo kikun A ko le seda won. Bi apeere: Iya:                  a ko le so pe        *i+ya   lo di       ‘iya’ Ori:                  a ko le so pe        *o+ri    lo di       ‘ori’ Omo:               a ko le so pe        *o+mo lo di      ‘omo’ Oba:                a ko le so pe        *o+ba  lo di      ‘oba’ Oro ti a seda ati oro-ipinle awon oke yii ko ni ijora itumo. Idi niyi ti a… Read More »OSE KERIN-IN

Yoruba

AARE BOOLU

Femi:         Boolu ale yii ko yoyo, o dun yato. Abi? Bayo:         Bee ni. Mo gbadun re gan an ni. Ki lo ri si ayo ti Kola gba wole ti Refiri fagi le un? Femi:         Mo rii. O dun mi wonu eegun. O dabi eni pe Refiri ti fon fere ki Kola to gba boolu naa s’awon. Pari iforowero yii. Lo awon gbolohun ibeere ati ede iepri to je mo are boolu afesegba.             AKORI EKO: ONA IBANISORO Ibanisoro ni ona ti eniyan meji tabi ju bee lo n gba fi ero inu won han si ara lona ti o fi ye won yekeyeke. Ona yii ni a n pen i ede. Ede ni o n fun ohun ti a n so ni itumo. Bi eni meji ti won ko gbo ede ara ba n soro, bi ariwo lasan no ohun ti won n so. Ni… Read More »AARE BOOLU

Yoruba

AKORI EKO: AROKO ONI-SORO-N-GBESI

Aroko ti a ko to da lori itakuroso laaarin eniyan meji tabi ju bee lo ni a n pen i aroko oni-soro-n-gbesi. Abuda Aroko Onisoro-n-gbesi O maa n ni akopa bii ere ori itage Oro enu akopa kookan maa n han ni iwaju oruko won Iso bee ko gbodo gun ju, ko si se regi Oro erin ati awada kii gbeyin, a si gbodo year fun awada ako Isesi won ni a maa n fi sinu ami akamo olofo ( ). E je ki a ka aroko oni-soro-n-gbesi yii wo, bi apeere: (Won sese gbe oga titun kan de si ile-iwe re, ko iforo-jomi-tooro oro to waye laarin akekoo meji lori oga titun yii sile). OGA TITUN (Ranti ati Yemisi wa ni Kilaasi S.S.2. Won pade ni ikorita meta ni eba ile ounje. Yemisi fe lo kawe, Ranti fe lo pon omi) Ranti:               (o sunmo Yemisi) E ma si ku… Read More »AKORI EKO: AROKO ONI-SORO-N-GBESI

Yoruba

AKORI EKO: ATUNYEWO ISE ABINIBI

Ise ni oogun ise                         Eni ise n se ko ma b’Osun                         Oran ko kan t’Osun                         I baa b’Orisa                         O di’jo to ba sise aje ko to jeun “Owuro lojo, ise la a fi i se ni Otuu’Fe”. Kaakiri ile Yoruba, ise ni won n fi owuro se. won gbagbo wi pe ‘Ise loogun ise’. Eredi ti won fi mu ise abinibi won ni okunkundun. Se ‘eni mu ise je, ko sai ni mu ise je’. Iran Yoruba lodi si imele, won gbagbo wi pe ‘owo eni ki i tan ni je’. Bi onikaluku ba ti ji idi ise ni won n gba a lo nitori ‘idi ise eni ni aa ti mo ni lole.’ Ibi ti baba bat i n sise ni omo yoo ti maa wo owo re, ti yoo si tibe maa ko o. won ni “Atomode de ibi oro n wo finnifinni, atagba… Read More »AKORI EKO: ATUNYEWO ISE ABINIBI

Yoruba

AKORI EKO: ATUNYEWO LORI SILEBU EDE YORUBA

Ninu oro ‘baba’ ege meji ni a ni: ‘ba-ba’. Ege kookan ni o ni iro faweli ati ami ohun. Ege kookan yii ni a n pe ni silebu. ABUDA SILEBU (i)         Silebu le je iro faweli kan tabi iro konsonanti ati faweli. Apeere:                                     i – ya                                     ba – ba                                     ko – bo                                     e – gbon (ii)        Iye ibi ti ohun ba ti je yo ninu oro kan ni yoo fi iye silebu ti oro naa ni han. Bi apeere: Ife        –          Ibi meji ni ohun ti je yo           (Silebu meji) Omuti –          Ibi meta ni ohun ti je yo          (Silebu meta) Ikadii   –          Ibi merin ni ohun ti je yo        (Silebu merin) IHUN SILEBU Apa meji ni silebu pin si. Awon ni: Odo silebu Apaala silebu (i)         Odo Silebu: Odo silebu ni ipin ti a maa… Read More »AKORI EKO: ATUNYEWO LORI SILEBU EDE YORUBA

Yoruba

AKORI EKO: AROKO AJEMO – ISIPAYA

Aroko ajomo-sispaya je aroko ti a fi n se isipaya awon ori oro to je mo ohun ayika eni. Aroko yii fi ara jo aroko asapejuwe sugbon o jinle ju u lo. Bi aroko asapejuwe se le fe ki o sapajuwe ‘Ile-iwe re’, aroko ajemo isipaya yoo fe ki a so nipa idagbasoke to de ba gbogbo nnkan ile iwe naa titi de ori eto isakoso. Aroko ajemo isipaya maa n tu isu de idi ikoko ijinle itumo, anfaani ati aleebu ori oro. Eyi tumo sip e aoko ajemo isipaya pe fun imo to gbooro nipa sisafihan bi nnkan won se ri tabi sise. Ki akekoo to le yege ninu aroko ajemo isipaya, o gbodo nifee si ise iwadii nipa nnkan ayika, ki o si ma aka orisirisii iwe, jona ati iwe-iroyin, ti yoo fun un ni imo kikun nipa nnkan ayika. Aroko ajemo isipaya le je eleyo-oro tabi apola… Read More »AKORI EKO: AROKO AJEMO – ISIPAYA

Yoruba

AKORI EKO: MOFIIMU

Mofiimu ni ege tabi fonran ti o kere julo ti o si ni ise ti o n se (tabi ihimo kikun) ninu ihunoro. Apeere eya moffimu ni oju, omo, owo, alaafia, eemi, egbon ati, ai, a, i, on. A ko le se atunge awon ege mofiimu oke wonyi mo ti a ba ge e, won yoo so itumo won nu. Eya Mofiimu A le pon mofiimu si orisii meji. Awon ni: Mofiimu Ipile (adaduro) Mofiimu afarahe MOFIIMU IPILE TABI ADADURO: eyi je ege ti o le da duro lai i ni afikun fonran (afomo) miiran pelu re. Mofiimu ipile maa n da itumo ni A ko le fo mofiimu ipile si wewe mo. Mofiimu ipile le je: ORO – ORUKO: oro oruko bayii kii gba afomo mora, bee ni a kole pinwon si meji tabi ki a seda won. Apeere: Adebisi, Igbokoda, Adaye, Omi, Ile, Ori abbl. ORO – AROPO… Read More »AKORI EKO: MOFIIMU

AKORI EKO: ATUNYEWO AAYAN OGBUFO

Aayan ogbufo ni itumo ede lati ede kan si omiran, paapaa julo ede geesi si ede Yoruba. Amuye for Ogbufo Gbigbo ede mejeeji: a gbodo gbo ede mejeeji daradara, eyi ni ede ti yoo tumo ati ede ti yoo tumo re si. Mimo ko ati mimo kaa: ogbufo gbodo le ka ede mejeeji daradara nitoripe akosile ede geesi ni won yoo gbe fun wa lati tumo. Apeere ogbufo gbolohun die Ede Geesi                                                                                Itumo lede Yoruba He was ashamed of his behaviour                                          Oju tii nitori iwaa re The headmaster permited the children to go home              Oga ile eko na fun awon akeeko laye lati lo sile The tortoise tricked the tiger and caged it at last                 Ijapa tan ekun naa je o sit i mo inu aago leyin – o – reyin It rained cats and dogs in Lagos yesterday                            Ojo ro ofeere wu oku ole ni ilu… Read More »AKORI EKO: ATUNYEWO AAYAN OGBUFO

Yoruba

AKORI EKO: ORAN DIDA ATI IJIYA TI O TO

Laye atijo ko si ofin ti a ko sile gege bi ti ode – oni. Sugbon, a no awon asa, eewo, ilana ti awon agba fi n se eto agbo ile ati akoso ilu. Bi o tile je pe ako ni akosile ofin naa gege bi a ti nii ninu iwe ofin lode oni, ole jija, ipaniyan, alonilowogba, ifipa – jale, ati iwa buburu gbogbo ti a n tun ri lode oni, ko to bee po rara. Eto idajo lori esun odaran lode oni ati ti aye atijo ko fi bee yato rara, gbogbo igbese bi ki agbo tie nu ti a fi esun kan a o si fun un laye lati pe eleri ti yoo ferii gbee leyin naa, a o se iwadi esun naa fin-ni-fin-ni. Ti o ba jare, a o daa sile ki o maa lo ni alaafia. Sugbon ti o ba jebi, a o fii ijayi… Read More »AKORI EKO: ORAN DIDA ATI IJIYA TI O TO

Yoruba

AKORI EKO: IYATO TI O WA LARIN ORO APONLE ATI APOLA APONLE

Oro aponle je eyo oro kan ninu ihun gbolohun ti o maa n pon oro – ise. Ise re gan-an ni lati se afihan itumo fun apola ise ninu gbolohun. Bi apeere: (i) Tunde rin: (ii) Tunde rin jaujau Tunde rin kemokemo Tunde rin pelepele Gholohun (i) je oro ise alaigbagbo (rin) ko I oro aponle eyi ti yoo je ki a mo bi oluwa se rin. Sugbon awon iso/oro abo gbolohun (ii) ni oro aponle to se afikun itumo oro-ise “rin” ni ekunrere. APOLA APONLE: Apola aponle je akojopo oro to n sise gege bi idi kan ti o si n pon oro-ise inu iso. Bi apeere: Ilu Osoosa maa n kun ni akoko odun agemo. Orisirisi apola aponle Apola aponle alasiko –  eyi n fi igba tabi asiko isele han. Bi apeere: Imole n mo nigba osan Okunkun n su nigba oru Ojo maa n po ni asiko… Read More »AKORI EKO: IYATO TI O WA LARIN ORO APONLE ATI APOLA APONLE

Yoruba

AKORI EKO: ORO AGBASO

Ohun ti o n bi oro agbaso nip e ko se e se fun eniyan lati wan i ibi gbogbo ti won ba n soro. Nigba ti eniyan ko basi tisi ni ibiti won bat i n soro kan o daju pe elomiran ti o wa nibe ni a n reti pe yoo wa so o fun eniyan. O se e se pe iwo ni yoo tun lo so fun elomiran ti o baye wipe oun naa ko si nibe ti iwa si wa nibe. Oro agbaso ni ona ti a n gab se atunso oro ti agbo lenu elomiran. Oro bee ni a n pen i sagbaso re e je eyi ti an tunso fun elomiran ti ko se alore tabi oro ti a n tun so fun eni ti oro naa koye to bi o tile je pe oun gan-an feti ara re gbo lati enu oloro. A… Read More »AKORI EKO: ORO AGBASO

Yoruba

AKORI EKO: EGBE AWO LORISIRISII

Ohun to soro lati mo kulekule ohun ninu egbe awo nitori won kofi eni ti kii se omo egbe idi niyi ti o fi je omo egbe lo le so pelu idaniloju ohun ti o n sele ninu egbe won. Orisirisii egbe awo ti o wa: Egbe ogboni (abalaye ati ti igbalode) Oro Egungun Agemo Imure Awo opa Pataki ise opolopo awon egbe awo wonyi ni fun idagbasoke ati alaafia ilu ti okan si n gbe ekeji ni igbonwo. Bi apeere, egbe oro wa fun sise abo ati eto ti o ye lori ipinnu ti o bati odo egbe ogboni wa nipa eto ilu. Tajateran ko nii se egbe ogboni, kaka bee o wa fun awon agba to ni ojo lori. Ko si fun odo obinrin afi awon ti o ti darugbo patapata ti Atari won to gbe eru awo. Bi apeere, Erelu okun. If ti o yii ni oso… Read More »AKORI EKO: EGBE AWO LORISIRISII

Yoruba

AKORI EKO – ETO OGUN JIJE LAYE ATIJO

Ogun jije se pataki pupo laarin awon Yoruba oun nii fi ilu alagbara han yato si ilu ti ko ni agba la. Orisii ogun meji ni o wa: Ogun ti a le pen i ogun adaja; ati Ogun ajadiju tabi ogun ajaku-akata: eyi le je ogun adugbo si adugbo, ileto si ileto tabi ilu si ilu Die ninu awon ti I ma fa si sigun si ileto tabi ilu miiran nwonyi. Gbigbe sunmoni Ote Ilara Ija aala ile Ija ile Ija fun igi owo bi ope, orombo, obi abbl Siisiigun lati fi pa oloye ogun ilu miiran n lenu mo Siisiigun lati fi ko ilu tabi ileto keji logbo nii Siisiigun lati fi agbara han Sisigun lati fi wa owo bi oda owo ba fe da ni Awon isise ti agbodo gbe ki a to segun Ifa dida Bibo ogun ati esu ati Pipolongo laarin ilu ki teruromo ilu lemo… Read More »AKORI EKO – ETO OGUN JIJE LAYE ATIJO

Yoruba

AFIWE ASA ISINKU ABINIBI ATI ETO ISINKU ABINIBI ATI ETO ISINKU ODE – ONI

Awon Yoruba gbagbe pe bi eniyan ba ku yoo lo si orun, yala orun rere tabi orun ti o ni iya ninu won gba pe bi eniyan ba ku, o tun le padawa ya lodo o mo re nipa bibi ige ge bi o mo. Orisii oku meji ni o wa gege bi ojo ori eni ti o saisi bat i n, awon nii: OKU OFO: eyi ti o tumo sip e iku omode (iku aitojo). Eni tiko dagba, yala nipa ijamba tabi aisan. Eyi je iku ibanuje laa rin awon Yoruba. OKU EKO: iru iku bayii niti awon agbalagba ti o ti darugbo kujekuje ti won re iwale asa, awon eni ti won ti gbe ile – aye as ohunribiribi ki won to ku. Afiwe asa isinke abinibi yato ge de rig be si eto isinku aye ode – oni nitori eto eru igba lode ti oti sun siwaju… Read More »AFIWE ASA ISINKU ABINIBI ATI ETO ISINKU ABINIBI ATI ETO ISINKU ODE – ONI

Yoruba

AKORI EKO: ITESIWAJU LORI ISORI ORO EDE YORUBA

Apeere gbolohun lori oro – oruko ni ipo alo: O mu emu Ajadi fo agbe Ekundayo ko ile alaja Oro oruko ni ipo eyan Okunrin oloro naa kun i afemojumo Aja ode pa etu nla Ewure Toorera ni won ji Ile olowo naa rewa ORISII ORO ORUKO Oruko eniyan –           Bisi, Dele Oruko eranko                        –           Kiniun, Obo Oruko bikan –           Ibadan, Oyo Oruko ohunkan –           Tabili, aso Oro Oruko afoyemo –           Idunnu, Ayo Oro oruko aseeke –           Owo, bata Oro oruko alaiseeka –           Omi, iyepe Oro oruko asoye Oro oruko aridinnu –           Ikoko, bata ORO – AROPO ORUKO (PRONOUN): A maa n lo oro aropo oruko ninu gbolohun lati dekun awitu n wi a sa n ninu gbolohun ede Yoruba. Apeere: ȩ, ǫ, won, mo, a, wa ati bee bee lo. Mo tele pa ile mo A lo si ipade awon afobaje ranaa Bukola ri won nibe A le… Read More »AKORI EKO: ITESIWAJU LORI ISORI ORO EDE YORUBA

Yoruba

AKORI EKO: ORO – ISE

Oro – ise ni oro tabi akojopo oro to n toka si isele tabi nkan ti oluwa se ninu gbolohun. Bi apeere: Ade ra iwe ede Yoruba Tuned gun igi osan “ra” ati “gun” ni opomulero to je oro – ise ti a fi mo nkan ti oluwa se ninu iso oke wonyii: Abuda oro – ise Oro – ise ni o maa n je yo leyin oluwa. Apeere: Ade je moinmoin Nike feran ese Oro ti o ba tele atoka iyisodi ko lo gbodo je oro –ise. Apeere: Bola ko je iyan Sunkanmi o wa Eya/ orisii oro – ise ORO – ISE KIKUN: Oro – ise ti o le da duro ti o sin i itumo kikun lai sip e a fi oro – ise miiran kun un. Bi apeere: Sade lo Bisi sun Kolade rerin-in Oro – ise kikun le je Oro – ise agbabo oro –… Read More »AKORI EKO: ORO – ISE

Coat of arms of Nigeria

YORUBA SS 3 SCHEME OF WORK

YORUBA SS 3- FIRST TERM Asá, Edè Ati Litireso I Ede: – Atunyewo leta aigbagbefe – Atunyewo isori oro – Aayan Ogbufo – Aranmo Asa: – Iwa omoluabi – Eto Ebi – Itesiwaju Ere Idaraya – Atunyewo Eto Iselu – Igbeyawo isinku ati ogun jiye Litireso: – Kiko ni mimo ise onkowe atinuda ( Ewi itan-aroso ere-onitan) – Ewi Apileko – itupale asayan iwe itan aroso meji   YORUBA SS 3- SECOND TERM Asá, Edè Ati Litireso II Ede: – Pipaje ati isunki – Atunyewo onka figo – Atunyewo Akaye – Atunyewo gbogbo isori gbolohun – Atunyewo Aroko ati Aroko Alariiyanjiyan – Itesiwaju ihun gbolohun : orisirisi awe gbolohun Asa: – Eto isomoloruko ati oruko Yoruba Litireso: – Atunyewo itan aroso oloro geere (gbogbo iwe) – Atunyewo Ewi Alohun Apileko (gbogbo iwe) – Atuupale iwe ere onitan (iwe meji) – Itupale Ewi Alohun (Asayan iwe meji)   Also See PHYSICS… Read More »YORUBA SS 3 SCHEME OF WORK

School Portal NG
error: Content is protected !!