Ise oro – Apejuwe at oro-aponle ninu gbolohun
Oro Apejuwe:-Eyi ni awon oro ti o n toka isele inu gbolohun . Oro oruko ni o maa n yan. Ise oro Apejuwe O le se ise eyan ninu gbolohu… Read More »Ise oro – Apejuwe at oro-aponle ninu gbolohun
Oro Apejuwe:-Eyi ni awon oro ti o n toka isele inu gbolohun . Oro oruko ni o maa n yan. Ise oro Apejuwe O le se ise eyan ninu gbolohu… Read More »Ise oro – Apejuwe at oro-aponle ninu gbolohun
Oro Oruko:- Oro Oruko ni awon oro ti won le da duro ni ipo oluwa, abo tabi eyan ninu gbolohun. Ise Oro-Oruko Oro-Oruko maa n sise oluwa ninu gbolohun –… Read More »ISE ORO ORUKO ATI ORO AROPO ORUKO NINU GBOLOHUN
Aroko ni ohun ti a ro ninu okan wa ti a si se akosile re. Aroko oniroyin je aroko ti o jo mo iroyin sise. Eyi le je kiko sile… Read More »AKOLE ISE- EDE: AROKO ATONISONA ONIROYIN (NARRATIVE ESSAY)
Gbolohun ni akojopo oro ti o ni oro-ise ati ise ti o n je nibikibi ti o ba ti jeyo. Eya gbolohun pin si ona meji Gbolohun Abode/eleyo oro-ise Gbolohun… Read More »Oriki Ati Eya gbolohun ede Yoruba pelu apeere (sentence)
Gbolohun ni afo ti o kun to si ni ise to n se nibikibi ti won ba ti je jade. Gbolohun ni iso ti o ni itumo kikun. Orisi eya… Read More »Ede:- Atunyewo orisirisi gbolohun ede Yoruba
Salako:- Kerekere odun 2015 n ko gba wole Adunni:- Olodumare ko wo aago enikan lati seto ijoba re Alake:- Ilu Ibadan ni emi ati egbon mi okunrin n lo lati… Read More »Ede:- Akaye onisoro-n-gbesi
Akaye: Akaye ni kika ayoka kan ti o ni itumo ni ona ti o le gba yei yekeyeke. Orisi ayoka ninu akaye Akaye oloro geere Akaye ewi Akaye oni isoro-n-gbesi… Read More »Ede:- ilana Kika akaye onisorongbesi
Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012) ASA:- Atunyewo asa iranra-eni lowo Asa irara-eni lowo ni ona ti opo eniyan… Read More »Ede:- Akaye oloro geere
Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012 Asa:- Ogun Jija (WAR/CONFLICT) Ona ti a le gba dena ogun Ki ife… Read More »Ede:- Akaye Oloro Geere wuuru
Aroko atonisona asotan ni aroko ti a fi n so nipa isele ti a fi oju wari tabi awon ise ti a gbo lenu enikan Ilana Fun Kiko Aroko Oniroyin… Read More »Ede:- Aroko Asotan/Oniroyin (Narrative Essay)
AKOLE ISE:- Ede:- Aroso Asotan/Oniroyinn Aroso asotan ni a fi n so nipa isele ti a fi oju wa ri tabi awon isele ti a gbo lenu enikan. Apeere Ori… Read More »OSE KERIN (NARRATIVE ESSAY)
Akole Ise: Ede – Aroko Alapejuwe
Aroko je ohun ti a ro ti a se akosile re
Aroko asapejuwe ni aroko ti a fi n se opejuwe bi eniyan, nnkan tabi ayeye se rig an-an.
Awon ori oro to je mo oroko asapejuwe
Aroso alapejuwe ni sise apejuwe eniyan, ibikan ati nnkan to sele gege bi a se rii g an-an pelu ohun enu. Aroso ni ki si ni akosile ohun enu ni… Read More »AKOLE ISE: EDE :AROSO ALAPEJUWE
Ose kin-in-ni: Ede-atuyewo ise saa kin-in-ni (onka 201-500) Asa-atuyewo ise saa kin-in-ni (asa isomoloruko) Litireso-Atunyewo litireso ninu ise saa kin-in-ni (ewi alohun to je mo ayeye) Ose keji: Ede… Read More »Eto ise fun saa keji
Igbeyawo ni isopo okunrin ati obinrin lati di took-taya ni ibamu pelu asa ati ilana isedale ile Yoruba. Koko mefa pataki ti o n gbe igbeyawo ni Ifesona (courtship) Ifayaran… Read More »ASA IGBEYAWO
Eyan ni awon wunren (oro) ti a fi n yan oro – oruko (noun) tai apola oruko (Noun phrase) ninu gbolohun tabi ninu isori. Bi apeere: Iwe tuntun ni a… Read More »AKORI EKO: EYAN
IGBESE LETA AIGBEFE Adiresi: Adiresi akoleta (The writer’s address) Adiresi agbaleta (Receiver’s address) Deeti (the day’s date) iii. Ikini ibeere (salutation) Akole leta (the tittle / heading) Koko leta (main… Read More »AKORI EKO: ATUNYENWO LETA AIGBEFE (INFORMAL LETTER)
Kin – in – ni awe gbolohun? Awe gbolohun ni ipede to ni oluwa ati ohun ti oluwa se Bi apeere: Ayinke mu omi Adepoju ti jeun Kasali je eba… Read More »AKORI EKO: IHUN ORISIIRISII AWE GBOLOHUN PO DI ODIDI GBOLOHUN
ASA IGBEYAWO ATIJO (IBILE) IGBESE IGBEYAWO ALAYE Ifojusode Awon obi okunrin yoo maa fi oju sile wa obinrin. Iwadii Won yoo se iwadii idile obinrin naa ni aarin ilu.… Read More »OSE KEFA ETO IGBEYAWO ABINIBI
Oge sise ni a n pe ni oso. Oso ara, oso ile. Ki a se itoju ara, aso, ile ni gbogbo e dale lori. Ki a se itoju irun: irun… Read More »ORISII ONA TI A N GBA SOGE NILE YORUBA