Skip to content

SS 2 Yoruba (1st Term)

Yoruba

Didaruko Faweli

A le fun awon iro faweli kookan ni oruko bayii: [a]        faweli airanmupe ayanupe (odo) aarin perese [e]        faweli airanmupe ahanudiepe (ebake) iwaju perese [ε]        faweli airanmupe ayanudiepe (ebado) iwaju perese [i]         faweli airanmupe ahanupe (oke) iwaju perese [o]        faweli airanmupe ahanudiepe (ebake) eyin roboto [ᴝ]       faweli airanmupe ayanudiepe (ebado) eyin roboto [u]        faweli airanmupe ahanupe (oke) eyin roboto   FAWELI ARANMUPE Didaruko Faweli: A le fun awon iro faweli kookan ni oruko bayii: [ā]        faweli aranmupe ayanupe aarin perese [ε]        faweli aranmupe ayanudiepe iwaju perese [i]         faweli aranmupe ahanupe iwaju perese [ᴝ]       faweli aranmupe ayanudiepe eyin roboto [ṻ]        faweli aranmupe ahanupe eyin roboto   AKORI EKO: ERO ATI IGBAGBO YORUBA LORI AKUDAAYA ATI ABAMI EDA IGBAGBO AWON YORUBA NIPA ASEYINWAYE Awon Yoruba ni igbagbo ti o jinle ninu aseyinwaye (iyen leyin iku) igbagbo ninu pipada wasiaye eni to ti ku yii wa ni aye atijo bee ni o si… Read More »Didaruko Faweli

Yoruba

OSE KESAN-AN

AKORI EKO: ATUNYEWO APEJUWE IRO KONSONANTI ATI IRO FAWELI Iro konsonanti ni awon iro ti idiwo maa n wa fun eemi ti a fi n gbe won jade. Idiwo le waye nipa ki ona eemi se patapata, ki iro jade pelu ariwo taki ki o se die ki iro jade ni irorun. Awon iro konsonanti ede Yoruba ni: d, b, f, g, gb, h, j, k, l, m, n, p, r, s, ṣ, t, w, y. ABUDA IRO KONSONANTI: Ti a ba fe se apejuwe iro konsonanti nipa abuda, a nilati wo awon ilana wonyi wo ni okookan: Orison eemi ti a fi n pe iro Irufe eemi ti a lo Ipo alafo tan-an-na Ipo afase Irufe afipe ti a lo Irufe idiwo ti o wa fun eemi Orisun eemi ti a fi pe iro: A nilati so orison eemi ti a lo lati pe iro konsonanti, yala Eemi edo-foro… Read More »OSE KESAN-AN

Yoruba

AKORI EKO: ATUNYEWO AWON EYA ARA IFO

“Eya ara ifo ni awon orisirisii eya ara ti a maa n lo fun pipe iro ede”. Abuda kan pataki ti o ya awa eniyan soto si awon eda yooku ni ebun oro-siso. Bi apeere, ti a ba so wi pe ‘Bawo ni nnkan’, awon eya ara kan wa ninu ara wa lati ori de ikun ti won jumo sise papo lati gba gbolohun ibeere yii jade. Awon eya ara bee ni a n pe ni eya-ara ifo. Aworan eye-ara ifo naa niyi:     AWORAN EYA-ARA IFO       ISORI EYA-ARA IFO A le pin awon eya-ara ifo si eya meji. Awon ni: (i) AWON EYA-ARA IFO AFOJURI: Awon wonyi ni eya-ara ifo ti a le fi oju ri nipa lilo digi tabi nnkan miiran. Awon naa ni: Afase, Olele, Iho imu Ita gogongo, Ete oke, Ete isale, Eyin oke, Eyin isale, Iwaju ahon, Aarin ahon, Eyin ahon,… Read More »AKORI EKO: ATUNYEWO AWON EYA ARA IFO

Yoruba

AKORI EKO: ITESIWAJU AWON ORISA ILE YORUBA

ORUNMILA ITAN NIPA ORUNMILA Okan pataki ni Orunmila je ninu awon okanlenirinwo Irunmole ti won ti ikole orun ro si Ofe Oodaye. Ni Oke Igbeti ni Orunmila koko de si ki o to lo si Oke Itase. Idi niyi ti won fi n ki i ni ‘Okunrin kukuru Oke Igbeti’. Orunmila ni alakoso Ifa dida ati tite ile. Owo re ni akoso aye nipa ogbon ati imo ohun ti yoo sele lojo iwaju wa. Ko si oro kan ni abe orun tabi oro kan nipa isenbaye, ogbon ati igbagbo awon Yoruba ti Ifa ko so nipa re. Gege bi Ojogbon ‘Wande Abimbola ti so ninu iwe “Awon Oju Odu Mereerindinlogun”, Orunmila lo opolopo odun ni Ife Oodaye, ki o to lo si Ado, ibi ti o ti pe ju lo ni ode aye. Idi niyi ti won fi n so pe ‘Ado n’ile Ifa’. Orunmila tun gbe ni Otu Ife.ibe… Read More »AKORI EKO: ITESIWAJU AWON ORISA ILE YORUBA

Yoruba

AKORI EKO: ITESIWAJU ONKA YORUBA

Igba mewaa (200 x 10) ni a n pe ni egbaa. A le wa ka a bayii: Onka Geesi Onka Yoruba Alaye ni Yoruba Alaye ni Geesi 2,000 4,000 6,000 8,000 10,000 12,000 14,000 16,000 18,000 20,000 Egbaa Egbaaji Egbaata Egbaarin Egbaarun-un Egbaafa Egbaaje Egbaajo Egbaasan-an Egbaawaa (oke kan) Igba lona mewaa Igba lona ogun Igba lona ogbon Igba lona ogoji Igba lona aadota Igba lona ogota Igba lona aadoje Igba lona ogoje Igba lona aadorun-un Igba lona ogorun-un 2,000 x 1 2,000 x 2 2,000 x 3 2,000 x 4 2,000 x 5 2,000 x 6 2,000 x 7 2,000 x 8 2,000 x 9 2,000 x 10   E je ki a lo egbaa lati se onka nipa fifi egbaa pin iye onka ti a ba fe ka, ji a to maa kaa loke loke. Onka Geesi Alaye ni Geesi Onka Yoruba Alaye ni Yoruba 30,000 32,000 34,000… Read More »AKORI EKO: ITESIWAJU ONKA YORUBA

Yoruba

AKORI EKO: ORISA ILE YORUBA

ITAN NIPA OGUN Ogun je okan pataki ninu awon okanlenirinwo irunmole ti won ti ikole orun wa si ile aye. A gbo pe nigba ti awon orisa n bo wa si ile aye, won se alabaapade igbo didi kijikiji kan. Orisa-Nla ni a gbo pe o koko lo ada owo re lati la ona yii sugbon ada fadaka owo re se. Ogun ni a gbo wi pe o fi ada irin owo re la ona gberegede fun awon orisa yooku lati koja. Ise ribiribi ti ogun se yii ni awon orisa yii se fi jeoye Osin-Imole ni ile-Ife. Itan fi han pe ode to ni okiki ni ogun. Tabutu ni oruko iya re. Baba re ni Ororinna. Won ni Ogun feran ise ode sise to bee to fi fi ilu sile lo si ori-oke kan ki o le ri aaye se ise ode. Igba ti ori-oke yii su un ni… Read More »AKORI EKO: ORISA ILE YORUBA

Yoruba

AKORI EKO: ITESIWAJU EKO LORI ONA IBANISORO

Ibanisoro ni ona ti eniyan meji tabi ju bee lo n gba fi ero inu won han si ara lona ti o fi ye won yekeyeke. Ona yii ni a n pen i ede. Ede ni o n fun ohun ti a n so ni itumo. Bi eni meji ti won ko gbo ede ara ba n soro, bi ariwo lasan no ohun ti won n so. Ni aye atijo, awon baba-nla wa kii fi gbogbo enu soro. Won gba wi pe ‘gbogbo aso ko la n sa loorun’. Awon ona kan wa ti won n gba ba eni to sun mo won, to wa nitosi tabi ona jijin soro lai lo enu. Se “Asoku oro ni je omo mi gb’ena”. Won a maa lo eya ara tabi fi nnkan miiran paroko ranse si won, ti itumo ohun ti won soyoo si ye won. Ni ode-oni ewe, irufe ona ibanisoro… Read More »AKORI EKO: ITESIWAJU EKO LORI ONA IBANISORO

Yoruba

OSE KERIN-IN

AKORI EKO: ATUNYEWO IHUN ORO Iro konsonanti ati iro faweli pelu ami ohun ni a n hun po di oro. Orisi oro meji ni o wa ninu ede Yoruba. Awon ni: Oro ipinle; ati Oro ti a seda ORO IPINLE: Oro ipinle ni awon oro ti a ko le seda won. Apeere: Adie, eedu, omi, ori, oju, imu, eti, apa, ese, owo, ile, oba, odo, ojo, agbara, omo, iya ati bee bee lo. Abuda Oro Ipinle Oro-ipinle maa n ni itumo kikun A ko le seda won. Bi apeere: Iya:                  a ko le so pe        *i+ya   lo di       ‘iya’ Ori:                  a ko le so pe        *o+ri    lo di       ‘ori’ Omo:               a ko le so pe        *o+mo lo di      ‘omo’ Oba:                a ko le so pe        *o+ba  lo di      ‘oba’ Oro ti a seda ati oro-ipinle awon oke yii ko ni ijora itumo. Idi niyi ti a… Read More »OSE KERIN-IN

Yoruba

AARE BOOLU

Femi:         Boolu ale yii ko yoyo, o dun yato. Abi? Bayo:         Bee ni. Mo gbadun re gan an ni. Ki lo ri si ayo ti Kola gba wole ti Refiri fagi le un? Femi:         Mo rii. O dun mi wonu eegun. O dabi eni pe Refiri ti fon fere ki Kola to gba boolu naa s’awon. Pari iforowero yii. Lo awon gbolohun ibeere ati ede iepri to je mo are boolu afesegba.             AKORI EKO: ONA IBANISORO Ibanisoro ni ona ti eniyan meji tabi ju bee lo n gba fi ero inu won han si ara lona ti o fi ye won yekeyeke. Ona yii ni a n pen i ede. Ede ni o n fun ohun ti a n so ni itumo. Bi eni meji ti won ko gbo ede ara ba n soro, bi ariwo lasan no ohun ti won n so. Ni… Read More »AARE BOOLU

Yoruba

AKORI EKO: AROKO ONI-SORO-N-GBESI

Aroko ti a ko to da lori itakuroso laaarin eniyan meji tabi ju bee lo ni a n pen i aroko oni-soro-n-gbesi. Abuda Aroko Onisoro-n-gbesi O maa n ni akopa bii ere ori itage Oro enu akopa kookan maa n han ni iwaju oruko won Iso bee ko gbodo gun ju, ko si se regi Oro erin ati awada kii gbeyin, a si gbodo year fun awada ako Isesi won ni a maa n fi sinu ami akamo olofo ( ). E je ki a ka aroko oni-soro-n-gbesi yii wo, bi apeere: (Won sese gbe oga titun kan de si ile-iwe re, ko iforo-jomi-tooro oro to waye laarin akekoo meji lori oga titun yii sile). OGA TITUN (Ranti ati Yemisi wa ni Kilaasi S.S.2. Won pade ni ikorita meta ni eba ile ounje. Yemisi fe lo kawe, Ranti fe lo pon omi) Ranti:               (o sunmo Yemisi) E ma si ku… Read More »AKORI EKO: AROKO ONI-SORO-N-GBESI

Yoruba

AKORI EKO: ATUNYEWO ISE ABINIBI

Ise ni oogun ise                         Eni ise n se ko ma b’Osun                         Oran ko kan t’Osun                         I baa b’Orisa                         O di’jo to ba sise aje ko to jeun “Owuro lojo, ise la a fi i se ni Otuu’Fe”. Kaakiri ile Yoruba, ise ni won n fi owuro se. won gbagbo wi pe ‘Ise loogun ise’. Eredi ti won fi mu ise abinibi won ni okunkundun. Se ‘eni mu ise je, ko sai ni mu ise je’. Iran Yoruba lodi si imele, won gbagbo wi pe ‘owo eni ki i tan ni je’. Bi onikaluku ba ti ji idi ise ni won n gba a lo nitori ‘idi ise eni ni aa ti mo ni lole.’ Ibi ti baba bat i n sise ni omo yoo ti maa wo owo re, ti yoo si tibe maa ko o. won ni “Atomode de ibi oro n wo finnifinni, atagba… Read More »AKORI EKO: ATUNYEWO ISE ABINIBI

Yoruba

AKORI EKO: ATUNYEWO LORI SILEBU EDE YORUBA

Ninu oro ‘baba’ ege meji ni a ni: ‘ba-ba’. Ege kookan ni o ni iro faweli ati ami ohun. Ege kookan yii ni a n pe ni silebu. ABUDA SILEBU (i)         Silebu le je iro faweli kan tabi iro konsonanti ati faweli. Apeere:                                     i – ya                                     ba – ba                                     ko – bo                                     e – gbon (ii)        Iye ibi ti ohun ba ti je yo ninu oro kan ni yoo fi iye silebu ti oro naa ni han. Bi apeere: Ife        –          Ibi meji ni ohun ti je yo           (Silebu meji) Omuti –          Ibi meta ni ohun ti je yo          (Silebu meta) Ikadii   –          Ibi merin ni ohun ti je yo        (Silebu merin) IHUN SILEBU Apa meji ni silebu pin si. Awon ni: Odo silebu Apaala silebu (i)         Odo Silebu: Odo silebu ni ipin ti a maa… Read More »AKORI EKO: ATUNYEWO LORI SILEBU EDE YORUBA

Yoruba

AKORI EKO: AROKO AJEMO – ISIPAYA

Aroko ajomo-sispaya je aroko ti a fi n se isipaya awon ori oro to je mo ohun ayika eni. Aroko yii fi ara jo aroko asapejuwe sugbon o jinle ju u lo. Bi aroko asapejuwe se le fe ki o sapajuwe ‘Ile-iwe re’, aroko ajemo isipaya yoo fe ki a so nipa idagbasoke to de ba gbogbo nnkan ile iwe naa titi de ori eto isakoso. Aroko ajemo isipaya maa n tu isu de idi ikoko ijinle itumo, anfaani ati aleebu ori oro. Eyi tumo sip e aoko ajemo isipaya pe fun imo to gbooro nipa sisafihan bi nnkan won se ri tabi sise. Ki akekoo to le yege ninu aroko ajemo isipaya, o gbodo nifee si ise iwadii nipa nnkan ayika, ki o si ma aka orisirisii iwe, jona ati iwe-iroyin, ti yoo fun un ni imo kikun nipa nnkan ayika. Aroko ajemo isipaya le je eleyo-oro tabi apola… Read More »AKORI EKO: AROKO AJEMO – ISIPAYA

School Portal NG
error: Content is protected !!