AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA (ILO OHUN)
Iro ohun ni lilo soke, lilo sodo ohun eniyan nigba ti a ba n soro. Iro ohun inu ede Yoruba pin si ona meji; Iro ohun geere Iro ohun eleyoo… Read More »AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA (ILO OHUN)