Skip to content

AKOLE ISE: ISOMOLORUKO

Yoruba

AKOLE ISE: ORIKI ATI ILANA KIKO AROKO YORUBA PELU APEERE

Aroko je ohun ti a ro ti a si se akosile re lori pepa ILANA FUN KIKO AROKO yiyan Ori-oro: A ni lati fa ila teere si abe ori-oro ti a n ko aroko le lori sise ilapa ero: A ni lati ronu jinle ki a si to ero okan wa ni okookan ninu ipinro kookan ki o le ye onkawe Kiko Aroko:- Alaroko gbodo ronu ohun ti o ye ki o je ifaara, ko gbodo gun ju Aarin aroko ni a o ti lo awon ojulowo koko oro bi a se lo won ninu ilapa ero. sipeli akoto ode-oni ni ki a fi ko aroko yii Ikadii:- eyi ni ipari aroko Ojulowo ede se pataki ninu aroko bii, Afiwe, akanlo ede abbl , ni akekoo gbodo se amulo.   ORISI AROKO Aroko atonisona alepejuwe Aroko asariyanjiyan Aroko atonisona oniroyin Aroko onileta Aroko ajemo – isipaya abbl   EKA ISE:… Read More »AKOLE ISE: ORIKI ATI ILANA KIKO AROKO YORUBA PELU APEERE

School Portal NG
error: Content is protected !!