A le fun awon iro faweli kookan ni oruko bayii: [a] faweli airanmupe ayanupe (odo) aarin perese [e] faweli airanmupe ahanudiepe (ebake) iwaju perese [ε]
Category: SS 2 Yoruba (1st, 2nd & 3rd Term)

AKORI EKO: ATUNYEWO APEJUWE IRO KONSONANTI ATI IRO FAWELI Iro konsonanti ni awon iro ti idiwo maa n wa fun eemi ti a fi n

“Eya ara ifo ni awon orisirisii eya ara ti a maa n lo fun pipe iro ede”. Abuda kan pataki ti o ya awa eniyan

ORUNMILA ITAN NIPA ORUNMILA Okan pataki ni Orunmila je ninu awon okanlenirinwo Irunmole ti won ti ikole orun ro si Ofe Oodaye. Ni Oke Igbeti

Igba mewaa (200 x 10) ni a n pe ni egbaa. A le wa ka a bayii: Onka Geesi Onka Yoruba Alaye ni Yoruba Alaye

ITAN NIPA OGUN Ogun je okan pataki ninu awon okanlenirinwo irunmole ti won ti ikole orun wa si ile aye. A gbo pe nigba ti

Ibanisoro ni ona ti eniyan meji tabi ju bee lo n gba fi ero inu won han si ara lona ti o fi ye won

AKORI EKO: ATUNYEWO IHUN ORO Iro konsonanti ati iro faweli pelu ami ohun ni a n hun po di oro. Orisi oro meji ni o

Femi: Boolu ale yii ko yoyo, o dun yato. Abi? Bayo: Bee ni. Mo gbadun re gan an ni. Ki lo ri si ayo ti

Aroko ti a ko to da lori itakuroso laaarin eniyan meji tabi ju bee lo ni a n pen i aroko oni-soro-n-gbesi. Abuda Aroko Onisoro-n-gbesi

Ise ni oogun ise Eni ise n se ko ma b’Osun Oran ko kan t’Osun I baa b’Orisa O di’jo to

Ninu oro ‘baba’ ege meji ni a ni: ‘ba-ba’. Ege kookan ni o ni iro faweli ati ami ohun. Ege kookan yii ni a n

Aroko ajomo-sispaya je aroko ti a fi n se isipaya awon ori oro to je mo ohun ayika eni. Aroko yii fi ara jo aroko