OSE KERIN (NARRATIVE ESSAY)

AKOLE ISE:-  Ede:-  Aroso Asotan/Oniroyinn

Aroso asotan ni a fi n so nipa isele ti a fi oju wa ri tabi awon isele ti a gbo lenu enikan.

Apeere Ori oro Aroso Asotan

  1. Ere boolu alafessegbe kan ti mo wo
  2. Ayeye ere onilejile ti o koja ni ile-iwe mi
  3. Isomoloruko omo egbon mi obinrin.

 

Igbelewon:-

  1. Kin ni aroso asotan
  2. So aroso lori isele kan ti o soju re

 

Ise Asetilewa:- So aroso lori isele kan ti o soju re

Asa: Asa ogun jija (WAR/CONFLICT)

“Oni koyi n pale ogun mo, edumare ma je ki o tenu mi bo”.  Eyi je okan lara owe ti Yoruba maa n pa nipa ogun jija laye atijo

Ogun ni ija laarin awon eniyan kan ni ilu tabi orile-ede ti o fa lilo awon ologun ati nnkan ija ogun

Ogun jija a maa wopo laarin awon Yoruba laye atijo nitori pe oun ni i fi ilu alagbara han yato si ilu ti ko ni agbara

  • Awon ohun ti o n fa ogun
  • Emi ilara
  • Ija lori aale ile
  • Gbigbija ilu ti a ni ife si
  • Sisigun lati fi wa owo bi ode owo ba fe da ni
  • Aayan ati ko dukia jo
  • Fifi agidi je oye idile ti ko to si ni
  • Yiye adehun lori isakole
  • Ojukokoro si oro ile atirandiran tabi nnkan ti ki i se teni
  • Obirin gbigba lona iwosi
  • Owo ayaasan
  • Efe ako ni dii ayo tita
  • Sisigun lati fi ko ilu tabi ileto kan logbon
  • Ija fun igi owo bi koko, o pe, orogbo, ataare abbl.

Awon Oloye Ogun

  1. Oranmiyan ni o de eto ati oye awon eso sile, oun ni eso kin-in-ni
  2. Olugbon
  3. Arese
  4. Onikoyi
  5. Olofa
  6. Balogun ootun, osi, asipa, ekerin, ekarun-un, abese, maye, ekefa, agbakin, aare, ikoleba, asaaju, ayingun, aare ago, jaguna, aare egbe omo Balogun.
  7. Aare onibon
  8. Seriki abbl.

 

Igbelewon :-

  1. Salaye eto ogun jija ni soki
  2. Ko ohun ti o le fa ogun marun-un
  • Se akosile awon oloye ogun

 

Ise asetilewa :-  yoruba Akayege iwe amusese fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012)  Oju Iwe kin-in-ni Eko kin-in-ni

 

LITRESO:-  KIKA IWE ESE-ONISE TI IJOBA YAN.

See also

OSE KETA (DISCRIPTIVE ESSAY)

AKOLE ISE: EDE :AROSO ALAPEJUWE

Eto ise fun saa keji

ASA IGBEYAWO

AKORI EKO: EYAN

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Get Fully Funded Scholarships

Free Visa, Free Scholarship Abroad

           Click Here to Apply

Acadlly