Skip to content

ORISII ONA TI A N GBA SOGE NILE YORUBA

Oge sise ni a n pe ni oso. Oso ara, oso ile. Ki a se itoju ara, aso, ile ni gbogbo e dale lori. Ki a se itoju  irun: irun didi, irun gige, iwe wiwe, enu fifo, ara pipa/jija eekanna gige ati bee bee lo ni a n pe ni imototo. Apeere oge sise nile Yoruba ni aye atijo ni ara finfin, eyin pipa, tiroo lile, laali, irun didi, enu fifo, ara pipa/jija ati bee bee lo. Eni ti o n maa n se itoju ara re ni a n pe ni afinju nigba ti a n pe eni ti ki i se itoju ara re ni obun.

 

Ara finfin: Ara finfin je okan lara oge sise ile Yoruba.Oloola (awon to maa n ko ila fun eeyan ) ni o maa n se ara finfin fun eeyan. Won le ya orisiirisii batani si ara eniyan bi alangba, Ooya idirun tabi akekee. Gbogbo nnkan won yii ni won n lo lati bu kun ewa  ara won.

 

Eyin Pipa: Eyin pipa ni asa ki a da iho tabi alafo si aarin eyin meji to wa laarin gbungbun enu. Awon Yoruba gba pe eni ti o ba ni eji maa n ni ewa. Awon oloola ni o maa n se eyi pelu.

 

Tiroo: Awon obinrin ni ni o maa n le tiroo ju. Won yoo maa fi igi iye ediye le si oju. O maa n wulo fun oju pipon ati eyikeyi arun oju. Awon iya olomo naa maa n lo o fun omode, ero won ni wi pe o maa n mu idoti kuro loju.

 

See also  ETO ISELU ODE-ONI

Laali: Awon obinrin maa n le laali si atelewo ati egbeegbe ese won mejeeji. Bi o ba gbe tan won yoo ko ewe laali yii kuro ni oju ibi ti won ti koo kuro yi maa n dudu lati bu kun ewa won.  Iru eyi maa n wopo ni Igbomina/Ilorin ati eya Hausa.

 

IGBELEWON:

 1. Kin ni oge sise?
 2. Ko ona merin ti a n gba soge laye atijo.

 

IWE AKATILEWA:

1          Eko ede Yoruba titun (SSS) iwe kin-in-Eko ede ati asa Yoruba iwe kin-in-ni (JSS 1) oju iwe 90 – 93 lati owo egbe akomolede ati asa Yoruba.

2          Eko ede Yoruba titun iwe kin-in-ni (J S S1 ) oju iwe 153-158 lati owo Oyebamji Mustapha.

 

 

APAPO IGBELEWON

 1. Fa 8lz s7 8d7 =r= 8se n7n5 zr0k[ y87:

On7r5ur5 kzy34f8 ni 9 k5n il3 ay3. Ol9w9 zti tql7kz l[ s6z. {l-gb-n 0un 0m6g= l[ bi r1rc. Ibi 8gb7n ti n sunk5n z8l9r7 ni zjznzk5 ti n pariwo or7 t7t9bi. Cni in5 n run n jow5 cni or7 n f-. Il3 ay3 y87 nqz ni K-l3dow9 ti bi [m[ m1j[ t7 Oy7b9y7 fi w[n dqj[, t7 8yq ol9w9 y[y[ wq di zgzn =sqn-an-gan.

 1. Salaye lori oge sise abinibi ile Yoruba.

 

ATUNYEWO EKO

 1. Salaye lori aseyinwaye.
 2. Salaye lori asa eewo nile Yoruba.
 3. Salaye lori eto abinibi nie Yoruba.

 

ISE ASETILEWA

 1. _____ ni opomulero fun gbolohun (a) oro-oruko (b) oro-ise (d) eyan
 2. E rowa ro ire je apeere oro-ise _____ (a) asoluwadabo (b) alapepada (d) agbabo
 3. Sola da obe nu. Oro_ise iru gbolohun yi ni (a) da (b) obe (d) danu.
 4. Awon wo lo maa n lo laali ju? (a) obinrin (b) okunrin (d) omode (e) arugbo
 5. Idi ti won fi maa n korin nibi ikomojade ati igbeyawo ni _________ (a) ounje jije (b) nitori ilu lilu ti o wa nibe (d) nitori a ki i saba korin lojoojumo (e) inu didun
See also  AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE

 

APA KEJI

 1. Salaye iyato meta laarin oro aropo oruko ati oro aropo aafarajoruko.
 2. Salaye iyato marun-un laarin oro oruko ati oro aropo oruko.
 3. Ko orisii ila marun-un ti awon Yoruba n ko.

 

See also

ETO ISELU ODE-ONI

ETO ISELU ABINIBI ATI ODE ONI

ISEDA ORO-ORUKO

ORO – AYALO

FONOLOJI EDE YORUBA

SUBSCRIBE BELOW FOR A GIVEAWAY

Building & maintaining an elearning portal is very expensive, that is why you see other elearning websites charge fees. Help to keep this learning portal free by telling mum or dad to donate or support us. We accept grants, sponsorships & support to help take this to the next big level and reach out to more people. Thank you so much. Click here to donate

Leave a Reply

Your email address will not be published.

School Portal NG
error: Content is protected !!