Skip to content

AWON ISE AKANSE ILE YORUBA

Yoruba

AWON ISE AKANSE ILE YORUBA

  1. Eni hihun
  2. Ikoko mimu
  • Irin riro
  1. Aro dida
  2. Igba finfin abbl.

Alaye lori die lara ise akanse ile Yoruba.

 

  1. ISE IKOKO MIMO: ise ikoko mimo wopo ni agbegbe Ilorin, oyo, ipetunmodun, ise obinrin ni ise ikoko mimo, awon ohun elo ikoko mimo ni wonyi; Amo, omi, odo, isaasun obe, ekusu agbado.

 

IGBESE MIMO IKOKO.

Gigun amo ninu odo pelu omi die, yoo mu dada.A oo gbe ikoko miiran/isaasun lati fi se ipinle bee ni a oo da oju ikoko naa de ile nipa mimo amo sii ni idi yika lati se odiwon ohun ti a fe mo.

 

Ti amo yii ba gbe die, a oo yo ikoko ti a fi se ipinle kuro, a oo si fi ekusu gbado se ona si ikoko ti a mo lara , a oo si sa sinu oorun.

 

Leyin ti o ba ti gbe tan, a o fi ina sun ikoko amo naa jinna daada.

 

  1. ISE AGBEDE

Okan lara ise ona ni ise yii je. Awon alagbede ni won n ro ohun elo bii, ada, oko, obe,

Irinse ise Agbede/irin riro ni wonyi

Owu Gbinrin Ikoko omi abbl
Omo owu Ewiri
Iponrin Emu

 

  1. ISE ARO DIDA

Kaakiri ile Yoruba ni ise aro-dida ti wopo. Ise obinrin ti o gba nini imo kikun nipa aro pipo, imo nipa awo ati batani ni ise aro-dida je.

 

Ohun elo-ise ni:  ikoko nla,omi, aro, orogun gigun/opa, paafa, aso teru, abbl.

Opa ti a fi n ro aro ninu ikoko aro ni a n pe ni “opa aro”.ori paafa” ni a n yo aso ti a yo ni aro si.

 

IGBESE ARO – DIDA

A oo fi aso teeru sinu aro fun iseju bi mewaa leyin naa, a oo ju aso naa si ori paafa, yoo lo bii iseju mewa pelu lori paafa.

 

Leyin iseju mewaa naa, a oo tun so pada sinu aro, eyi ni a oo se titi aso naa yoo fi dudu bi a se fe. Ni gba ti o ba ti mu abajade ti a fe jade,  a oo yo kuro ninu aro lati sa.

 

See also

Kika Iwe Apileko Oloro Geere Ti Ijoba Yan

EYA GBOLOHUN

AKOLE ISE

AKOLE ISE

ATUNYEWO AMI OHUN ATI SILEBU EDE YORUBA

SUBSCRIBE BELOW FOR A GIVEAWAY

More Suggestions

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *