Mr. Shodiya

Yoruba

EYA GBOLOHUN

Gbolohun Onibo Eyi ni gbolohun ti a fi gbolohun miiran bo inu re.   Gbolohun onibo pin si; Gbolohun onibo asaponle Gbolohun onibo asapejuwe Gbolohun onibo asodoruko   Gbolohun Onibo asaponle Eyi ni gbolohun ti a fi n se aponle ninu gbolohun nipa lilo oro atoka “ti” tabi “bi”. Apeere. Awon ole yoo sa bi […]

EYA GBOLOHUN Read More »

Yoruba

AKORI EKO: ERE IDARAYA

Ere idaraya ni awon ere t tewe – tagba maa n se lati mu ki ara won jipepe. Bi awon Yoruba se feran ise – sise to bee naa ni won ni akoko fun ere idaraya. Akoko ti ise ba dile tabi awon eniyan ba dari bo lati ibi ise oojo won ni won maa

AKORI EKO: ERE IDARAYA Read More »

Yoruba

ASA ISINKU NI ILE YORUBA

Isinku ni eye ikeyin ti a se fun oku. Ni ile Yoruba, ayeye isinku agba je ohun Pataki ti o fese mule ni awujo awon Yoruba paapaa ti o ba je agbalagba ti o fi owo rori ku. Inawo ati ipalemo oku maa n po fun awon molebi ati ana oku. Gbogbo molebi oku ti

ASA ISINKU NI ILE YORUBA Read More »

Yoruba

AKOLE ISE: AROKO KIKO

Aroko ni atinuda ero eni, ti a ko lori ori oro kan Pataki si inu iwe fun onkawe lati ka. Orisi aroko ti o wa niyi; Aroko oni leta Aroko onisorogbesi Aroko alariyanyan Aroko alapejuwe Aroko ojemo – isipaya Aroko atonisona asotan Aroko oniroyin Awon ilana to se Pataki fun aroko kiko Yiyan ori-oro: A

AKOLE ISE: AROKO KIKO Read More »

Yoruba

AKOLE ISE: SILEBU

Silebu ni ege oro ti okere julo ti a le pe jade ni enu ni ori isemii kan soso Batani / Ihun Silebu Ihun silebu maa n toka si awon ege iro otooto ti won n je yo ni apa silebu.     Apeere apa silebu ni wonyi; APA ALEYE APEERE ORO APA (a)    Odo

AKOLE ISE: SILEBU Read More »

Yoruba

EKA ISE: EDE

AKOLE ISE: ATUYEWO AWON EYA ARA – IFO (EYA ARA ISORO) Eya ara ifo ni eya ara ti a maa n lo fun gbigbe iro ifo jade A le pin eya ara ifo si isori meji, awon ni; Eya ara ifo ti a le fi oju ri: apeere: ete oke, ete isale, eyin oke, e

EKA ISE: EDE Read More »

Yoruba

Didaruko Faweli

A le fun awon iro faweli kookan ni oruko bayii: [a]        faweli airanmupe ayanupe (odo) aarin perese [e]        faweli airanmupe ahanudiepe (ebake) iwaju perese [ε]        faweli airanmupe ayanudiepe (ebado) iwaju perese [i]         faweli airanmupe ahanupe (oke) iwaju perese [o]        faweli airanmupe ahanudiepe (ebake) eyin roboto [ᴝ]       faweli airanmupe ayanudiepe (ebado) eyin roboto [u]        faweli airanmupe

Didaruko Faweli Read More »

Yoruba

OSE KESAN-AN

AKORI EKO: ATUNYEWO APEJUWE IRO KONSONANTI ATI IRO FAWELI Iro konsonanti ni awon iro ti idiwo maa n wa fun eemi ti a fi n gbe won jade. Idiwo le waye nipa ki ona eemi se patapata, ki iro jade pelu ariwo taki ki o se die ki iro jade ni irorun. Awon iro konsonanti

OSE KESAN-AN Read More »

Get Fully Funded Scholarships

Free Visa, Free Scholarship Abroad

           Click Here to Apply

Acadlly