Mr. Shodiya

Yoruba

AMI OHUN

Ede Yoruba je ede ami ohun. Opolopo ni ede ti won maa n se amulo ohun ni orile-ede yii ati kaakiri agbaye. Ara won ni ede faranse. Faweli ni o maa n gba ami sori pelu konsonati aranmupe asesilebu ‘’m ati n’’ Ninu ede Yoruba, oro eyokan pelu sipeli kanna le ni opolopo itumo paapaa […]

AMI OHUN Read More »

Yoruba

IRO KONSONANTI

Iro konsonanti-; ni iro ti a pe nigba ti idiwo wa fun eemi ti o n ti inu edofooro bo.iro konsonanti mejidinlogun lo wa ninu ede Yoruba. Awon naa ni; b,d, f, g, gb, h, j, k, l, m, n, p, r, s, s, t, w, y. APEJUWE IRO KONSONANTI AKOONU Iro Konsonanti: ni iro

IRO KONSONANTI Read More »

Yoruba

IRO FAWELI

Iro-Ede -; ni ege ti  o kere julo ti a le fi eti gbo ninu ede, ti a ba n ba eniyan soro ,iro ifo ni ohun ti eni naa yoo maa gbo. A le ko iro –ede sile nipa lilo leta tabi ami.Iro-ede ti a ni pin si ona meta; Iro faweli Iro konsonanti

IRO FAWELI Read More »

Yoruba

EYA ARA IFO

Eya ara ifo ni awon eya ara ti a fi maa n pe iro jade ni enu. Apeere ni: iho imu, kaa enu, aja enu, tan-an-na, gogongo, komookun, edo fooro, ete oke, ete isale, eyin oke, eyin isale, erigi oke erigi isale, eyin ahon, iwaju ahon, eyin ahon.   EYA ARA IFO EYA ARA IFO

EYA ARA IFO Read More »

Yoruba

ORUNMILA

Orunmila ni alakoso ifa. O si je okan pataki ninu awon orisa ile Yoruba. Oke Igeti ni Orunmila koko duro si ki o lo si oke *tas2. O lo opolopo odun ni Ife Ondaye ki o to lo si Ado. Ibi ti o tip e julo ni ode aye. Idi niyi ti won fi n

ORUNMILA Read More »

Yoruba

AWON ORISA ILE YORUBA

Ona meji pataki ni a le pin awon orisa ile Yoruba si.  Awon orisa kan wa to je pe won ro wa lati orun,  orisa ni Olorun da won, won ki i se eniyan nigba kan kan ri. Awon orisa ipin keji ni awon eniyan ti a so di orisa nitori ise  ribiribi owo won

AWON ORISA ILE YORUBA Read More »

Yoruba

ORO-ORUKO NI ILANA APETUNPE

AKOONU A le seda oro-oruko nipa sise apetunpe. Apetunpe yii pin si ona meji: eyi ni apetunpe kikun ati elebe.  A le se Apetunpe Kikun fun Oro-Oruko Apeere: Kobo  +          kobo   =          kobokobo Odun  +          odun   =          odoodun Ale      +          ale       =          alaale Osu     +          osu      =          osoosu Osan   +          osan    =          osoosan Egbe  

ORO-ORUKO NI ILANA APETUNPE Read More »

Yoruba

AYOKA ONISOROGBESI

Ka ayoka isale yii,ki o si dahun ibeere ti o tele e Ayo;               O da a,aanu re lo se mi O mo on so, o dun lete re bi oyin N o gba o si  egbe wa. Baba Ramo     Haa! E seun o. Mo dupe o. Ayo                 Sugbon owo iwegbe re n ko-

AYOKA ONISOROGBESI Read More »

Yoruba

AROKO AJEMO ISIPAYA

Aroko ajemo isipaya je aroko ti o gba sise alaye kikun nipa nnkan ayika eni. Bi apeere aroko alaye ekunrere lori bi won se n se ounjeti a feran julo yato si pa ki a se apejuwe re. Apeere aroko ajemo-isipaya ni: Ise Tisa Oge Seise. Aso Ebi Ise ti mo fe lojo iwaju. Ki

AROKO AJEMO ISIPAYA Read More »

Yoruba

Ede:- Akaye onisoro-n-gbesi

Salako:-         Kerekere odun 2015 n ko gba wole Adunni:-        Olodumare ko wo aago enikan lati seto ijoba re Alake:-                       Ilu Ibadan ni emi ati egbon mi okunrin n lo lati se odun Salami :-        Awon awako n sare asa pajude loju popo ni asiko yi o Adunmi :-      Bi o se emi ati ile mi, buburu kan

Ede:- Akaye onisoro-n-gbesi Read More »

Yoruba

Ede:- Akaye oloro geere

Yoruba Akayege fun ile eko sekondiri kekere iwe keji lati owo L. Orimogunje, K. Adebayo, F. Okiki(2012) ASA:-  Atunyewo asa iranra-eni lowo Asa irara-eni lowo ni ona ti opo eniyan fi n pawopo ran eniyan kan lowo se ise ti iba gba ni lasiko. Ipa Ti Asa Iranra-Eni Lowo N Ko Ninu Ise Ajumose At

Ede:- Akaye oloro geere Read More »

Get Fully Funded Scholarships

Free Visa, Free Scholarship Abroad

           Click Here to Apply

Acadlly