AKOLE ISE: SISE OUNJE AWUJO YORUBA

Ouje ni awon ohun ti eniyan ati aranko n je tabi mu ti o fun ara wa ni okun ati agbara. Won ni “Bi ebi ba kuro ninu ise, ise buse. Ouje ni oogun ebi.

Ise Agbe ni ise ti o gbajumo julo ni ile Yoruba, awon agbe yii ni on pese ire-oko ti eniyan ati eranko n je bii isu, ewa, agbado, gbaguda, eso lorisirisi bii, igba, ope, oyinbo, orogbo, asala, agbalumo, oronbo, obi abbl.

Ire oko ati bi a se n se won

  • Iyan: Isu

A o be isu le na, ti isu ba jina, a o tu si odo. A o gun, bee ni a o ma ta omi sii titi yoo fi fele bi eti ti a o ko sinu abo fun jije pelu obe to gbamuse bii, efo riro tabi isapa.

  • Amala: Ogede

Bi ogede ba ti gbe, won yoo lo o kuna . Elubo yii ni won yoo dasi omi hiho, ti a o fi omorogun ro o titi ti yoo fi dan. Leyin eyi ni a o fa sinu abo tabi inu ora iponmola. Obe gbegiri dara lati fi je amala ogede

  • Aadun: Agbado

Ti a ba ti yan agbado, a o loo kuna. A o wa egeere epo ati eree ti a ti se,  ti a si din, won yoo ro epo ati eree yii mo agbado ti a lo. Aadun de niyen

LITIRESO:  OGBON ITOPINPIN LITIRESO EDE YORUBA

 

Koko ti a ni lati mo ti a ba n ko iwe litireso niyi:

  1. Koko-oro (theme):  Litireso apileko gbodo ni koko oro ti onkowe fe ki a mo tabi kogbon
  2. Ilo-ede (use of language): onkowe kookan ni won ni batani ilo-ede won. Bi apeere, fagunwa faran owe, asodun ati awitunwi, bee ni olu owolabi feran akanpo owe ati akanlo-ede. Die lara ona ede ti a lo ba pade ninu litireso ni wonyi; owe, akanlo-ede, afiwe taara, afiwe eleloo, awada, asorege, ifohun-peniyan, ifohundara, awitunwi abbl.
  3. Asa Yoruba (Yoruba culture): Asa je mo ajumohu iwa ati ise awon eniyan kan. Die lara asa ile Yoruba ni, ikini, igbayewo, isomo loruko, itoju omo, iranra-eni lowo, isinku, oge sise iwa omoluabi, ogun jije, ise sise, ogun jije abbl.
  4. Eda itan (character): eda itan ni onirunru eniyan ti o kopa ninu litireso alohun tabi apileko. Eni ti o kopa ju lo ninu isele inu litireso kan ni olu ede itan

Ni opo igba, oruko awon eda itan wonyi maa n fi ero, iwa ati ise won han

  1. Ibudo itan: Eyi ni ibi, agbegbe tabi ilu ti isele inu itan ti waye.

Igbelewon:

  • Fun iro konsonanti loriki
  • Salaye isori iro konsonanti ni sisentele
  • Kin ni ounje?
  • Ko ire oko marun un ki o si salaye bi a se n se won
  • Salaye koko ti onkowe gbodo mo bi o ba n ko iwe litireso

Ise asetilewa: bawo ni a se n se ounje ile Yoruba wonyii:

  1. Gbegiri
  2. Ekuru
  3. ikokore

 

See also

AKOLE ISE: ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE

EKO LORI IGBADUN TI O WA NINU LITIRESO ALOHUN

ITESIWAJU LORI EKO IRO EDE YORUBA

EKA ISE: EDE

EKA ISE: EDE

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Get Fully Funded Scholarships

Free Visa, Free Scholarship Abroad

           Click Here to Apply

Acadlly